GV

GeezerVison

The World Wide Web, restored to 800 pixels of glory.

Home|About|Gaming cabinet|Archives|How it works|Starter sites

On this site

  • BBC News, Yorùbá
  • Wò
  • Gbọ́
  • Idibo Naijiria 2027
  • Eré ìdárayá
  • Èyí to gbajúmọ̀ jù

This view

  • Original page
  • New address

GeezerVison is showing www.bbc.com — Àbáwọlé - BBC News Yorùbá

BBC News, Yorùbá - Ìròyìn

Ìròyìn tó ṣe kókó

  • Aworan awọn olukopa nibi eto ipade alaafia.

    Ètò ìdìbò 2027: Ìṣẹ̀lẹ̀ rògbòdìyàn 109 ló ti wáyé lórí ọ̀rọ̀ òṣèlú láwọn ìpínlẹ̀ ní Nàìjíríà ní ìtàpá sí àdéhùn àlááfíà tó wà nílẹ̀

    Igbimọ ọhun ti Ọgagun Abdulsalami Abubakar alaga rẹ sọ pe akọsilẹ awọn agbeyẹwo ti awọn ṣe laaarin ọjọ kọkandinlogun, oṣu Kẹjọ si ọjọ kẹtadinlọgbọn, oṣu Kẹwaa fi han pe eto idibo ọdun 2027 wa ninu ewu.

    ìṣẹ́jú 26 sẹ́yìn
  • Aworan Toyosi Adesanya

    Fídíò,
    Iṣẹ́ abẹ márùn ún ni mo ṣe nítorí àti bímọ, ọkọ mi wọ aṣọ kan náà fún ọjọ́ mẹ́sàn án kí n lè bímọ - Toyosi Adesanya

    Toyosi Adesanya sọ pe ''ọdun mẹẹdogun ni mo lo ninu igbeyawo mi akọkọ ti n ko si ri ọmọ bi nibẹ.''

    wákàtí 3 sẹ́yìn
  • Oloyan ti ilu Oyan, Oba Adekeye Oluyeye, wọ agbada pẹlu irukẹrẹ lọwọ, Gomina Ademola Adeleke wọ buba olomi buluu ati fila olomi ọsan.

    Owó oṣù méje ni Gómìnà Adeleke ń jẹ àwa Ọba l'Osun, ọ̀pọ̀ Ọba ló ń ṣàìsàn tí kò rówó ra oògùn - Oloyan ìlú Oyan ké gbàjarè

    Oloyan ti ilu Oyan ni ''ọṣẹ marun un ni mo fi gba itọju nile iwosan LUTH niluu Eko, mo ṣẹṣẹ pada wale ni.''

    11 Bélú 2026
  • Aworan Ashamu
    7:05

    Fídíò,
    Awọn ọ̀dọ́ ní iṣẹ́ láti ṣe lórí ọ̀rọ̀ ìṣèjọba àti ìdàgbàsókè - Ashamu, olùdíje ilé aṣojúṣòfin nípínlẹ̀ Oyo, Duration 7,05

    11 Bélú 2026
  • Aworan ẹnu aafin Awujalẹ ati Kabiyesi Awujalẹ to waja.

    Ṣé lóòótọ́ làwọn jàǹdùkú kò já ààfin Awujale gbà? Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Ogun ṣàlàyé

    Ninu atẹjade kan ti agbẹnusọ ọlọpaa ọlọpaa Ogun, Oluseyi Babaseyi sọ pe awọn da ọlọpaa si aafin naa lati mojuto eto aabo nibẹ ni, ki wọn si ri daju pe ohun gbogbo n lọ letoleto.

    11 Bélú 2026
  • Aworan Gomina Adeleke pẹlu ẹrọ gbohungbohun lọwọ, aworan apo owo kan wa niwaju rẹ.

    Wọ́n ní Gómìnà Adeleke jẹ gbèsè kún gbèsè l'Osun, àmọ́ Gómìnà Osun ní pínrín òun kò yá owó kankan látòkè òkún!

    Gomina Adeleke n sọ pe awọn ijọba to kọja ni wọn n ka si oun lọhun.

    11 Bélú 2026
  • Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
    0:59

    Orin,
    Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́, Duration 0,59

    Àkójọpọ̀ ìròyìn káàkiri àgbáyé tí kò ṣe è má gbọ̀ ọ́

    11 Bélú 2026
  • Iwe irinna ilẹ Ghana aṣia ati ontẹ orilẹede Ghana

    Gbàǹjo pásípọ́ọ̀tù! Ohun tí a mọ̀ rèé nípa àwọn tó ń ta ìwé ìrìnnà 'diplomatic passport' fáwọn tí kò tọ́ sí

    Awọn ọmọ ẹgbẹ to kere julọ nile aṣofin orilẹede naa lo ke gbajare yii sita.

    11 Bélú 2026
  • Awọn ṣọja meji to n wo ori oke kan ninu igbo

    Fún sísá lójú ogun, ṣọ́jà 66 gba ìdájọ́ ikú

    Ileeṣẹ ologun ilẹ naa sọ pe oun ṣe eyi lati fi awọn to yẹ jofin, kawọn yooku naa le huwa to tọ bi wọn ṣe n koju ikọ to n da ilu laamu ni Ila-Oorun DR Congo.

    11 Bélú 2026
  • Oluwo ti ilẹ Iwo, Ọba AbdulRasheed Akanbi, wọ agbada ofi ati fila pẹlu ilẹkẹ lọrun, Gomina Ademola Adeleke wọ agbada funfun ati fila pupa

    Mi ò sí lábẹ́ ẹnikẹ́ni, abẹ́ Ọlọ́run nìkan ni mo wà, Oluwo sọ̀rọ̀ sókè lẹ́yìn tó gba lẹ́tà ìkìlọ̀ láti ọ̀dọ̀ ìjọba Osun

    Oluwo to sọrọ ninu fidio kan eyi to ti lu ori ayelujara pa sọ pe ''Ọba alaye ni mi, ọba si maa n ba a lori ohun gbogbo ni.''

    10 Bélú 2026
  • Awọn arinrin-ajo kan ree ninu ọkọ oju omi

    Arìnrìn-àjò mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n kú, ọ̀pọ̀ farapa nínú ìjàmbá ọkọ̀ ojú omi ní Senegal

    Minisita fọrọ eto abẹle ni Senegal ti fidi rẹ mulẹ pe awọn omuwẹ ti doola ẹmi ẹnikan ni wọn ri doola, bo tilẹ jẹ pe ko tii sẹni to le sọ pato iye awọn to wa ninu ọkọ oju omi naa.

    10 Bélú 2026
  • Bola Tinubu wọ agbada buluu pẹlu fila

    Wo àwọn nǹkan tí Ààrẹ Tinubu ń gbèrò láti ṣe fún aráàlú tó bá wọlé sáà kejì

    Aarẹ Tinubu sọrọ yii ninu alakalẹ eto ti ẹgbẹ oṣelu APC sọ pe awọn ni fun ọdun 2027 titi de 2031, bi ẹgbẹ naa ba jawe olubori pẹlu ibo araalu.

    10 Bélú 2026
Fo Móríwú kọjá kí o tẹ̀síwájú

Móríwú

  • Temilolu Nurudeen Ashamu wọ asọ toke tilẹ ati agbada alawọ buluu, o si de fila to ba mu. O duro, o ka ọwọ mejeeji papọ siwaju rẹ
  • Francis Olusegun wọ asọ oye bii akẹkọjade tii se alawọ omi aro, o wọ shaati funfun sabẹ rẹ, o si de tai pupa sọrun. O tun de fila asọ ikẹkọjade naa
  • Awọn ọmọ ẹgbẹ akọrin lọkunrin lobinrin, awọn ọkunrin wọ toke tilẹ alawọ waini nigba ti awọn obinrin wọ kaba alawọ pupa
  • Obinrin kan to n sare lori papa wọ asọ alawọ ewe ati funfun
  • Ọkunrin to wọ asọ toketilẹ alawọ buluu ati fila awọn eeyan loke Ọya
  • Iyawo Oyedokun wọ asọ leesi funfun, o we gele pọpu
  • Olusegun Obasanjo wọ asọ toketilẹ alawọ funfun ati fila pọpu, o mu ẹrọ amohunbugbẹmu lọwọ alaafia rẹ
  • Obinrin to wọ kaba alaranbara, o lo irun oloyinbo wiigi
  • Oloogbe Olayemi Bayonle Bolaji wọ asọ toketilẹ olomi waini, o duro siwaju ile kan
  • Abimbola Adekanmbi wọ asọ toke tilẹ funfun, o ke fila alarambara, o pa ọwọ rẹ mejeeji pọ lasiko to n sọrọ
  • Apẹja kan to wọ asọ buluu pẹlu fila
  • Olushola Olonade ati ọkọ rẹ, Segun, wọ asọ kaba ati agbada toke tilẹ alawọ omi aro, ọkọ de fila pupa nigbati aya de ate pupa

Ìparí Móríwú

BBC News Yorùbá ti wà lórí ìkànnì WhatsApp

Má jẹ́ kí etí rẹ ó di sí gbogbo ìròyìn ohun tó ń lọ ní Naijiria àti káàkiri àgbáyé. Mọ̀ nípa wọn lórí ìkànnì Whatsapp rẹ

Darapọ̀ mọ́ wa lórí WhatsApp

Ìròyìn Àkàgbádùn

  • Opeyemi Falegan Ati Nkechi Blessing dijọ wọ asọ alawọ ewe, wọn fi ilẹkẹ sọrun

    Àlàyé rèé lórí bí Nkechi Blessing ati ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ àtijọ́, Opeyemi Falegan ṣe parí ìjà; àmọ́ ṣé ọ̀rọ̀ ìfẹ́ tún padà sáàrin wọn bí?

    Bi ẹ ko ba gbagbe, losu kẹrin ọdun 2022, aarin awọn mejeeji lo daru, ti ọrọ ifẹ wọn si daru gidi, koda, wọn ko ara wọn wa sori ayelujara, ti wọn si n sọ oko ọrọ sira wọn.

    10 Bélú 2026
  • Daniel Craig pẹlu akẹgbẹ rẹ, Léa Seydoux

    James Bond: Ohun tí a mọ̀ nipa fíìmù 007 tuntun tó ń bọ̀ lọ́nà

    Ninu awọn fiimu diẹ to n bọ, awọn alakoso ere gbiyanju lati mu ifẹgbẹkẹgbẹ ba ohun to ti kọja, nipasẹ yiya ara wọn ni diẹ ninu apap ere itan naa to dabi arosọ tabi aṣeju. Wọn ko si tun fara mọ gbogbo aṣa, ilana ati awọn abuda ti a mọ si ti Bond bi wọn ṣe maa n tẹle.

    10 Bélú 2026
  • Awọn ọdọ meji jokoo sinu okunkun pẹlu atupa laarin wọn

    Ilé-iṣẹ́ amúnáwá DisCos tọrọ àforíjìn, ṣàlàyé ohun tó ṣokùnfà òkùnkùn birimù lásìkò ooru yìí

    Ọpọ onibaara lo ti n kerora latari bi wọn ko ṣe ri ina ọba lo daadaa mọ, papaa julọ pẹlu ooru to n mu lasiko yii.

    10 Bélú 2026
  • Ibọn meji nilẹ

    Àlàyé rèé lórí báwọn agbébọn ti ṣekúpa èèyàn mẹ́tàlá nínú ẹbí kan ṣoṣo

    Lopin ọsẹ to kọja ni awọn agbebọn ṣẹkọlu si idile kan labule Gidan Taba nijọba ibilẹ Maradun nibi ti wọn ti pa ọkunrin kan ati gbogbo idile rẹ.

    9 Bélú 2026
  • Baba Ijesha wọ aṣọ funfun, o de fila funfun, o n wo ọọkan

    Àwọn òjíṣẹ́ Ọlọ́run méjì ló ṣèkilọ̀ ohun tó gbé mi dé ọgbà ẹ̀wọ̀n fún mi ṣùgbọ́n mi ò gbọ́ ìkìlọ̀ - Baba Ijesha

    Baba Ijesha sọ pe oludasilẹ ijọ Love of Christ Generation Church ti ijọ Cherubim ati Seraphim, iranṣẹ Ọlọrun, Abimbola Ajayi ati oludasilẹ ijọ Genesis Global Ministry, Pasitọ Israel Ogundipe ti ọpọ mọ si Genesis ni wọn ṣekilọ naa fun oun.

    9 Bélú 2026
  • Omoyele Sowore wọ aso toketilẹ funfun, o gbe ilẹkẹ nla sọrun, o si lo awo oju dudu
    2:26

    Fídíò,
    Ayálégbé ni Tinubu ní Aso Rock, dúkìá gbogbo wa ni – Owoyele Sowore, Duration 2,26

    Sowore lo sọrọ naa lasiko to n ba BBC sọrọ nipa lẹta kan ti AAC kọ si ijọba apapọ pe ẹgbẹ oun fẹ lo ile ijọba ọhun fun eto ẹgbẹ rẹ.

    2 Bélú 2026
  • Issac Valdez to kọ lati gba ẹjẹ wọ asọ alawọ buluu, o de fila siwaju, o si lo awo oju, awọn igi ati igbo wa lẹyin rẹ

    Wo ọkùnrin ọmọ ijọ́ Ajẹ́rìí-Jehofa tó kú torí ó kọ̀ láti gba ẹ̀jẹ̀ àmọ́ lẹ́yìn ọjọ́ díẹ̀, ìjọ́ yí òfin mágbẹ̀jẹ̀ padà

    Ofin ijọ Ajẹrii- Jehofa ti yipada lori ilana gbigba ẹjẹ, amọṣa o ti pẹju fun arakunrin naa. Lẹyin ọjọ mẹtalelogun to ku nitori aifẹgbẹjẹ nitori ofin ijọ naa ni ijọ yi ofin ọ̀hun pada

    9 Bélú 2026
  • Pasitọ Joel wọ asọ toketilẹ alawọ buluu, o pa ọwọ rẹ pọ, o n rẹrin musẹ
    2:31

    Fídíò,
    "Lóòótọ́ ni mò ń rówó lẹ́yìn tí mo ṣoògùn owó àmọ́ n kò le kọ́lé tàbí ra ọkọ̀", Duration 2,31

    BBC News Yoruba ba Pasitọ Joel sọrọ nipa igbinyanju rẹ lati se oogun owo ati ipẹyinda rẹ.

    31 Ọ̀wàrà 2026
  • Toluwanisings, Oloogbe naa

    Ètò ìsìnkú Toluwanisings ń lọ lọ́wọ́ nílùú Ibadan

    Bi ẹ ko ba gbagbe, ọjọ kẹrinla, oṣu Kẹwaa, ọdun 2026 ni Toluwanisings jade laye, nigba ti awọn mọlẹbi rẹ sọ pe niṣe lo deedee ṣubu lulẹ.

    9 Bélú 2026
  • Ọpọ ero nibi ijamba ọkọ reluwe naa

    Fídíò,
    Èèyàn méje kú, àwọn tó lé lọ́gọ̀rún farapa níbi ìjàmbá reluwé tó wáyé ní Egypt

    Awọn alakoso reluwe lorileede naa sọ pe ọkọ reluwee meji lo fori sọ ara wọn lasiko ti awọn mejeeji n rin irin ajo.

    9 Bélú 2026
  • Paul Makenzie

    Pásítọ̀ tó ṣokùnfà ikú èèyàn 191 rí ẹ̀wọ̀n igba ọdún he

    Ọkunrin naa, to pe ara rẹ ni pasitọ kọkọ ko sọwọ ọlọpaa ninu ọdun 2023 lẹyin ti wọn ṣawari oku eeyan to le ni irinwo ninu igbo Shakahola to wa lẹba eti okun Kenya.

    9 Bélú 2026
  • Pasito Adeboye ati Ola Olukoyede

    Pasitọ Adeboye dá ọ̀pọ̀lọpọ̀ bílíọ̀nù náírà owó jìbìtì tí ọmọ ìjọ kan fi ta ṣọ́ọ̀ṣì RCCG lọ́rẹ̀ padà fún EFCC

    EFCC jẹ ko di mimọ pe ni kete ti awọn ti fi iṣẹlẹ naa to Pasito Adeboye leti, lo ti paṣẹ pe ki wọn da awọn owo naa pada.

    8 Bélú 2026

Ìròyìn Pàtàkì

  • Awọn eeyan to n dibo naa lasiko to n lọ lọwọ

    Wo kókó mẹ́rin tàwọn awòye sọ pe o mú ẹgbẹ́ òṣèlú Democrats borí nínú ìbò ìdajì sáà kejì l'America

    5 Bélú 2026
  • Bola Tinubu wọ buba buluu ati fila, Joe Ajaero wọ aṣọ dudu

    Awuyewuye lórí ₦70,000 owó ìrànwọ́ tí Tinubu kéde fáwọn òṣìṣẹ́, ọ̀pọ̀ èèyàn kọminú pé ọpọ ọmọ Naijiria ni kò lánfààní sówó náà

    4 Bélú 2026
  • Bimbo Adekanmbi
    7:58

    Fídíò, Ilà Gọmbọ ojú mi ni wọ́n n pè ní 'Local Government Autonomy' nipinlẹ Oyo, mo fọwọ síi- Adekanmbi, Duration 7,58

    4 Bélú 2026
  • Ibi ti baalu naa ja si

    Ọkọ̀ òfúrufú já lulẹ̀, gbogbo èrò inú rẹ̀ jáde láyé

    3 Bélú 2026

Kọ́milẹ́kọ̀ọ́

  • Aarẹ Bola Tinubu ju ọwọ sawọn ero nibi ipolongo ibo

    Wo bí o ṣe lè mọ̀ bó yá o wà lára àwọn ọmọ Naijiria tí yóò jẹ ànfààní ₦50,000 tí ìjọba Tinubu ń pín fáwọn mẹ̀kúnnù

    7 Bélú 2026
  • Awọn maaluu nla to ni awọ funfun ati awọ yẹpẹ pupa.

    Ohun tó yẹ kí o mọ̀ nipa Shamonda, kòkòrò àrún tó ṣẹ́yọ́ ní Nàìjíríà, tó ti gbẹ̀mí èèyàn kan ní France

    24 Ọ̀wàrà 2026
  • Obinrin to n wo foonu rẹ

    Wo àwọn nǹkan márùn-ún tí o le fi dènà ọrùn dúndùn

    10 Ọ̀wàrà 2026
  • Aworan ileepo NNPC kan ati  aworan aarẹ Tinubu

    Ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa àdínkù owó epo bẹntiróòlù tí ìjọba Nàìjíríà kéde

    9 Ọ̀wàrà 2026

Ẹ tẹ̀lé wa lórí ìkànnì ayélujára

  • Facebook
  • Instagram
  • WhatsApp

Móríwú

  • Odo ti baaluu ologun jabọ si n'Igbokoda

    Inú ebi la wà, a ń rí ẹ̀yà ara èèyàn lórí omi tí bààlúù ológun jábọ́ sí n'Igbokoda-Araalu

    3 Bélú 2026
  • Aisha Yusuf Ojora wọ aṣọ funfun
    2:15

    Fídíò, Ẹ wo ìbẹ̀rẹ̀ ayé Aisha Yusuf Ojora, ọmọ atàpátadìde tò di igbákejì akọ́nimọ̀ọ́gbá fun Super Falcons, Duration 2,15

    31 Ọ̀wàrà 2026
  • Aworan ina to jo sọọbu
    1:31

    Fídíò, Iná ṣọṣẹ́ lọ́jà Gbagi n'Ibadan, àwọn ọlọ́jà ń bèèrè ìrànlọ́wọ́ ìjọba, Duration 1,31

    31 Ọ̀wàrà 2026
  • Habibat Jinadu wọ asọ leesi iro ati buba alawọ buluu ati funfun, o we gele ati ipele funfun pẹlu baagi ati ẹgba ọrun funfun
    2:27

    Fídíò, 'Nítorí pé èèyàn kan fi mí we ọ̀bọ ló jẹ́ kí n lọ bóra', Duration 2,27

    31 Ọ̀wàrà 2026
  • Okunrin kan jokoo sibi ti ko fi apẹẹrẹ ọla han, o to awon iwe kan siwaju

    Ìjọba àpapọ̀ fẹ́ máa fún àwọn ọmọ Naijiria tí ìṣẹ́ ń ṣẹ́ ní 50,000 lóṣù

    31 Ọ̀wàrà 2026
  • Akẹyinsi ori ọmọbinrin kan
    1:56

    Fídíò, "Àádọ́ta mílíọ̀nù ni wọ́n ní ká san fún ìtúsílẹ̀ wa", Duration 1,56

    31 Ọ̀wàrà 2026
  • Aworan awọn orilẹede to wa nilẹ Afirika
    3:31

    Fídíò, Kí ló dé tí ọrọ̀ ajé Áfíríkà ń dàgbà sókè, àmọ́ tíìgbé ayé adúláwọ̀ ń rẹ̀yìn?, Duration 3,31

    31 Ọ̀wàrà 2026

Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn

  • Adelana Adekunle Solomon tawọn eeyan mọ si Oba Solomon, tabi Oba Agbaye

    Ẹ má sunkún tí mo bá kú, àrá máa sán pa ẹni tó bá ké nítorí mi- Oba Solomon

    Ninu fidio kan loju opo Instagram ni Oba Solomon ti wọ aṣọ adura to si n ba awọn ọmọ ijọ rẹ sọrọ naa.

    7 Bélú 2026
  •  Junior Ezeonu,Carol Kazeem ati Oye Owolewa ti won n rerin

    Èyí ni àwọn ọmọ Naijiria-America mẹ́rìnlá tó yege ìbò sáà kejì l'America

    Alaga ileeṣẹ to n ri si ọrọ awọn ọmọ Naijiria loke okun, 'Nigerians in Diaspora Commission', Abike Dabiri-Erewa, ṣapejuwe aṣeyọri naa bii idagbasoke lẹyin odi.

    7 Bélú 2026
  • Awọn akọrin Loud Urban Choir

    'Bí eré, bí àwàdà la fi bẹ̀rẹ iṣẹ́ orin kíkọ̀' - Ẹgbẹ́ akọrin Loud Urban Choir

    Aṣoju ẹgbẹ naa, Funmi Arewa lasiko to n ba BBC sọrọ, jẹ ko di mimọ pe bi ere, bi awada ni awọn fi bẹrẹ iṣẹ orin kikọ naa, ko to di pe o burẹkẹ mọ wọn lọwọ.

    9 Bélú 2026
  • Brand Russell

    Russell Brand: Adẹ́rìnpòṣónú rí ẹ̀wọn ọdún mẹ́wàá àti oṣù mẹ́fà he fún ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀ àti aṣemáṣe

    Nigba to n ṣapejuwe Brand, Adajọ Joel Bennathan to gbe idajọ naa kalẹ sọ pe ikooko ajeegunjẹran ni labala aṣemaṣe ibalopọ.

    10 Bélú 2026
  • Atiku Abubakar lapa osi, Aarẹ Bola Tinubu lapa ọtun

    A kò lọ́wọ́ nínú ìdájọ́ tó yọ Atiku kúrò lára àwọn olùdíje sípò ààrẹ- APC

    Akọwe ikede apapọ fun APC, Felix Morka, sọ pe awọn ẹgbẹ alatako maa n tete di ẹbi ru APC nigbakigba ti idajọ ile ẹjọ ko ba ri bi wọn ṣe fẹ.

    7 Bélú 2026
  • Awọn ọmọ Ogbomoso

    Kí ni pàtàkì àyẹyẹ àyàjọ́ Ogbomoso tó máa ń wáyé lọ́dọdún?

    ‎Ninu ipade awọn akọroyin to waye ninu aafin Soun ti ilẹ Ogbomoso, Alaga igbimọ fun ayẹyẹ naa, Ọgbẹni Segun Dokun Odebunmi, ṣalaye idi ti ilu Ogbomoso fi n ṣe ayẹyẹ naa lọdọdun.

    7 Bélú 2026
  • Aare Bola Tinubu

    Kóòtù gba ẹ̀rí ìjọba wọlé, tako ẹ̀bẹ̀ ológun mẹ́fa tí wọ́n ní wọ́n fẹ́ gbàjọba mọ́ Tinubu lọ́wọ́

    Adajọ Joyce Abdulmalik, kọ alaye tawọn eeyan naa ṣe pe awọn ologun fipa mu awọn jẹwọ ẹṣẹ ninu fidio ti won ti gba ohùn ẹnu awọn kalẹ lori ẹsun naa ni.

    6 Bélú 2026
  • Awọn osisẹ eleto ilera mẹta n tọju obinrin kan to sun sori ibusun ninu ọkọ pajawiri

    Lẹ́yìn ikú Toluwanisings, ilé aṣòfin àgbà dábàá kókó méjìlá fún ìtọ́jú aláìsàn pàjáwìrì àti ìjìyà ẹ̀wọ̀n oṣù mẹ́fà fún títako àbá náà

    Aba atunse ofin eto ilera naa, eyi ti Sẹnatọ Abdulaziz Yar'Adua se onigbọwọ rẹ, lo wa lati se atunse si ofin eto ilera tọdun 2014.

    6 Bélú 2026
  • Kọmiṣọnna ọlọpaa ipinlẹ Osun, Ibrahim Zungura to wa ninu aṣọ ọlọpaa

    Afurasí mẹ́rin dèrò àtìmọ́lé l'Osun lórí ẹ̀sùn ìpànìyàn àti gígé orí òkú

    Nurudeen Ademakinwa, ẹni ọgbọn ọdun ti wọn tun n pe ni Igboya Aye-Nuru; Agboluaje Usman, ẹni ọdun mẹtalelogun; ati Awoniran Toheeb, toun jẹ ọmọ ogun ọdun ni awọn mẹtẹẹta tọwọ kọkọ tẹ niluu Ikirun.

    5 Bélú 2026

Àwọn Ìròyìn Kàyééfì míràn

  • Eyiyemi Afolayan wọ asọ alawọ pinki, o n rẹrin, na ọwọ mejeeji soke
    1:59

    Fídíò, Níbo Layé Kọjú Sí?: Kí lobìnrin ń fẹ́ lára ọkùnrin gan? Eyiyemi Afolayan dá sí ìbéèrè yí, Duration 1,59

    24 Ọ̀wàrà 2026
  • Aworanni kan to n kirun.

    Wọ́n yọ ìmáàmù nípò, wọ́n ló ń fi wáàsí polongo sáà kejì fún Tinubu

    23 Ọ̀wàrà 2026
  • Broda Shaggi

    'Ìgbà tí mo fi ọwọ́ kan itan mi tí mo rí ẹ̀jẹ̀ ni mo tó mọ̀ pé ọta àṣìta ìbọn ti bà mí' Broda Shaggi, ṣàlàyé ohun tó mú kó di àwátì lórí afẹ́fẹ́

    22 Ọ̀wàrà 2026
  • Aworan Funkẹ Akindele ati Toyin Abraham.

    Ọ̀rọ̀ láàárín Toyin Abraham àti Funke Akindele tún súyọ lórí ayélujára, ohun tí a mọ̀ rèé

    20 Ọ̀wàrà 2026

Ife Ẹ̀yẹ Àgbáyé 2026/Eré Ìdárayá

  • Ẹgbẹ agbabọọlu Flamingos lasiko ti wọn gba ife ẹyẹ agbaye U-17 lorileede Morocco

    Wo àwọn kókó márùn-un tó jẹ́ kí Flamingos gba ife ẹ̀yẹ U-17 fún ìgbà àkọ́kọ́

    8 Bélú 2026
  • Agbabọọlu Naijiria ati awọn agabbọọlu Brazil ree lasiko ifẹsẹwọnsẹ naa

    Ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù Flamingos ti Nàíjíríà pegedé fún ipele àṣekágbá ìdíje U-17 ti àwọn obìnrin fún ìgbà àkọ́kọ́

    5 Bélú 2026
  • Harry Kane to wọ asọ kootu oloyinbo, n fi ẹnu ko bọọlu dudu kan ti wọn fi goolu se

    "Mo rí ìrírí òkè àti pẹ̀tẹ́lẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ ìṣẹ́ bọ́ọ̀lù gbígbá, àwọn èèyàn kò lérò pé mo le di ààyò nídìí bọ́ọ̀lù gbígbà - Harry Kane tó gba àmì ẹ̀yẹ Ballon d'Or sọ̀rọ̀ akin

    27 Ọ̀wàrà 2026
  • Agbabọọlu lati ilẹ Afirika n gba ami ẹyẹ
    2:34

    Fídíò, Ṣé ó ṣeéṣe kí ọdún 2026 mú àyípadà bá ìtàn àmì ẹ̀yẹ Ballon Dior fáwọn agbábọ́ọ̀lù láti Áfíríkà?, Duration 2,34

    26 Ọ̀wàrà 2026
  • Suliat Abideen wọ asọ ere idaraya, o kun irun ori rẹ ni awọ pupa
    2:25

    Fídíò, Wọ́n máa ń nà mí tí mo bá lọ gbá bọ́ọ̀lù láì kiri ẹja àmọ́ lónìí, mo di ìlúmọ̀ọ́ká agbọ́bọ́ọ̀lù - Suliat Abideen, Duration 2,25

    19 Ọ̀wàrà 2026
  • Tiwa Savage wọ aṣọ olomi buluu, Teniola wọ agbekọ

    Ṣé lóòótọ́ ni Teniola àti Tiwa Savage yóò wàákò nínú ẹ̀ṣẹ́ kíkàn láti gba ₦1.5bn? Ohun tí a mọ̀ rèé

    4 Ọ̀wàrà 2026
  • Nkechi n gbaradi fun ija.

    Ẹ jẹ́ kí n padà sí sinimá ṣiṣe, ó hàn pé mí ò kí ń ṣe ẹlẹ́ṣẹ́ – Nkechi Blessing sọ̀rọ̀ lẹ́yìn tí wọ́n jàn án mọ́lẹ̀ pẹ̀lú ẹ̀ṣẹ́

    2 Ọ̀wàrà 2026
  • Àwọn agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà márùn-ún, níbi ti àwọn mẹ́rin ti wọ aṣọ funfun tí adilémú ti wọ aṣọ aláwọ̀ ewé

    Eré bọ́ọ̀lù ní Naijiria ń kojú ìṣòro tó lágbára lọ́wọ́ yìí – Segun Odegbami

    27 Owewe 2026

Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ

  1. 1
    Iṣẹ́ abẹ márùn ún ni mo ṣe nítorí àti bímọ, ọkọ mi wọ aṣọ kan náà fún ọjọ́ mẹ́sàn án kí n lè bímọ - Toyosi Adesanya
  2. 2
    Owó oṣù méje ni Gómìnà Adeleke ń jẹ àwa Ọba l'Osun, ọ̀pọ̀ Ọba ló ń ṣàìsàn tí kò rówó ra oògùn - Oloyan ìlú Oyan ké gbàjarè
  3. 3
    Mi ò sí lábẹ́ ẹnikẹ́ni, abẹ́ Ọlọ́run nìkan ni mo wà, Oluwo sọ̀rọ̀ sókè lẹ́yìn tó gba lẹ́tà ìkìlọ̀ láti ọ̀dọ̀ ìjọba Osun
  4. 4
    Ṣé lóòótọ́ làwọn jàǹdùkú kò já ààfin Awujale gbà? Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Ogun ṣàlàyé
  5. 5
    'Ó lè pa wá o': Àwọn olùgbé Kenya figbe ta lórí àkóbá El Niño pẹ̀lú àfojúsùn àgbàrá
  6. 6
    Wọ́n ní Gómìnà Adeleke jẹ gbèsè kún gbèsè l'Osun, àmọ́ Gómìnà Osun ní pínrín òun kò yá owó kankan látòkè òkún!
  7. 7
    Fún sísá lójú ogun, ṣọ́jà 66 gba ìdájọ́ ikú
  8. 8
    Wo bí o ṣe lè mọ̀ bó yá o wà lára àwọn ọmọ Naijiria tí yóò jẹ ànfààní ₦50,000 tí ìjọba Tinubu ń pín fáwọn mẹ̀kúnnù
  9. 9
    Wo àwọn nǹkan tí Ààrẹ Tinubu ń gbèrò láti ṣe fún aráàlú tó bá wọlé sáà kejì
  10. 10
    Ètò ìdìbò 2027: Ìṣẹ̀lẹ̀ rògbòdìyàn 109 ló ti wáyé lórí ọ̀rọ̀ òṣèlú láwọn ìpínlẹ̀ ní Nàìjíríà ní ìtàpá sí àdéhùn àlááfíà tó wà nílẹ̀
You are visitor 01402503 — GeezerVison does not store the pages you look up.
Best viewed with Netscape Navigator 4.7 or Internet Explorer 6 at 800×600. No cookies required.